【實用書籍app】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)|最夯免費app

【實用書籍app】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)|最夯免費app

分享好友

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ.. A ti fi ọpọlọpọ awọn ẹya ohun mere mere lati jẹki kika ati iwadi ti Bibeli re gbẹgẹ.Wa’diO le lo ohun elo iwa’di iṣẹ lati wa ẹsẹ Bibeli lori ero kan pato. Kọ rọra tẹ ọrọ ti ohun wa ki ‘app’ si gbe ẹsẹ ti o jẹmọ jade si ọ.Fi awọn ẹsẹ han lori Facebook, Twitter ati EmailNi bayi o le fi ẹsẹ lati nu Bibeli han awọn ọrẹ rẹ taara lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ Email (ki o si fi erongba ọkan rẹ han).Kọ Adura ati awon eroỌpọlọpọ awọn ti nlo ate eto wa n beere fun ohun ti wọn le lo lati le kọ awọn àdúrà wọn, ero tabi oro ti won gba nigbati wọn ba n ka Bibeli wọn. Ṣẹda adura arare ati ero re, fi wọn pamọ sinu awọn ‘app’ ati paapa fi wọn han si awọn ọrẹ rẹ lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ emailIsaami si ẹsẹNibayi o le saami ti o yatọ si awon ẹsẹ bibeli pelu awọn awọ ti o ba wu ọ. kọ rọra tẹ aworan geege nigba ti o ba n ka ọrọ Bibeli lọwọBayi o le ri ese ti o yatọ ninu àwo ti o fẹ. Ko tẹ awọn aami ohun elo ikọwe bi o ba ka awọn ọrọ BibeliBukumaakiBukumaaki yio ran ọ lọwọ lati sami si ibi tire ninu ọrọ bibeli. Awọn aami bukumaaki yi ni owa loke iboju. kọ fi ika tọ lati sami sori rẹ. Nigba ti o ba pada si ‘app’ tẹ aami ti owa loke ti iboju, yio si gbe ọ lọ sibi ti o ti kuro.Wa ki o si se afiwe awọn ẹsẹ (Ni App)Awọn ‘app’ yi ni o ni "iboju wẹẹrẹ" ti o jẹ ki o sese fun o lati wo ẹsẹ meji ni akoko kan na ati ki o le ka ki o si ṣe afiwe wọn l’ẹgbẹ ara won.Ọpa Ìkẹkọọ - Išė AkojọṢẹda awọn iwe aṣẹ eleyọ tabi olọpọ ẹsẹ. Fi iwadi rẹ si ẹgbẹẹ àwọn ẹsẹ ọun. O le se ifiwe ran se (email) awọn iwe aṣẹ lati nu ‘app’.Eda King James ni ede oyiboKa bibeli ti eda King James ni ede oyibo. Se afiwe awon ẹsẹ kankan lati nu eda ti Swedish pelu tie de oyibo.Pe WaA n reti awọn esi rẹ. A ma n gbọ a si tun mu awọn ohun titun sinu ‘app’ na nipase awon arọwa yin. O le fi iwe ranṣẹ si wa nipasẹ awọn olubasọrọ wa ninu iṣẹ ‘app’ yi.

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

【免費書籍App】Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)-APP點子

免費玩Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) APP玩免費

免費玩Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) App

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) APP LOGO

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) LOGO-APP點子

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) APP QRCode

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) QRCode-APP點子
熱門國家系統支援版本費用APP評分上架日期更新日期
未知iOS
App Store
1.0
App下載
$2.99
2015-05-062015-06-04
分享app
上一個APP
下一個APP

高評價書籍App推薦

Bread

Comprehensive bread baking directory containing many different bread ideas. Learn how to prepare yeast and knead dough so that your breads come out of …
PINOYPUB

Welcome to PINOYPUB! PinoyPub brings each and every one our very own Pinoy Romance pocketbooks and e-publications through easy and simple online readi …
楽学

いつでもどこでも、勉強ができる、便利なアプリケーション四択問題も兼ね備えた単語帳です。単語帳で暗記勉強、四択問題で試験を受けてみてください。正解率100%で☆がコレクションできます。Ver2.1.0 (2010/06/23)・単語WEB検索機能Ver2.0.0 (2010/06/22)・グラフィック …